“Ògòngò lọba ẹiyẹ” – “Ostrich is the King of Birds”
Ògòngò – Ostrich. Courtesy: @theyorubablog Ògòngò jẹ ẹiyẹ ti ó tóbi jù ninú gbogbo ẹiyẹ, ẹyin rẹ ló tún tóbi jù. Ọrùn àti ẹsẹ̀ rẹ ti ó gún jẹ́ ki ó ga ju gbogbo ẹiyẹ yoku....
View Article“Ti ibi, ti ire la wá ilé ayé” –Ọ̀rọ̀ àti Ìṣe Ìgboro ni Èkó: “We came into...
Èkó jẹ́ olú ìlú Nigeria fún ọpọlọpọ ọdún, ki wọn tó sọ Abuja di olú ìlú Nigeria, ṣùgbọ́n Èkó ṣi jẹ́ olú ìlú fún iṣẹ ọrọ̀ gbogbo Nigeria. Nitori eyi, gbogbo ẹ̀yà Nigeria àti àwọn ará ìlú miran titi dé...
View ArticleÀwòrán ati Orúkọ àwọn Ẹiyẹ ni èdè Yorùbá – Pictures and names of...
Originally posted 2014-10-17 13:00:55. Republished by Blog Post Promoter
View ArticleYí Yára bi Ojú-ọjọ́ ti nyí padà nitori Èérí Àyíká – Effect of...
Ẹ wo àròkọ “Yí Yára bi Ojú-ọjọ́ ti nyí padà nitori Èérí Àyíká” lóri ayélujára ni ojú ewé yi: Check out the essay on “Effect of environmental pollution on rapid climate change” on our...
View ArticleBi mo ṣe lo Ìsimi Àjíǹde tó kọjá – How I spent the last Easter Holiday
Ìsimi ọdún Àjíǹde tó kọjá dùn púpọ̀ nitori mo lọ lo ìsimi náà pẹ̀lú ẹ̀gbọ́n Bàbá mi àti ẹbí rẹ ni ilú Èkó. Èkó jinà si ilú mi nitori a pẹ́ púpọ̀ ninú ọkọ̀ elérò ti àwọn òbí...
View ArticleKòkòrò – Names of Insects & Bugs in Yoruba
Kòkòrò jẹ́ ohun ẹ̀dá kékeré tó ni ìyẹ́, ti ó lè fò, òmíràn kò ni iyẹ́, ṣugbọn wọn ni ẹsẹ̀ mẹfa. Ẹ ṣe àyẹ̀wò àpẹrẹ, àwòrán àti pi pè ni ojú ewé wọnyi. ENGLISH TRANSLATION Insects...
View ArticleBi ọmọ ò jọ ṣòkòtò á jọ kíjìpá: Ibáṣe pọ Idilé Yorùbá – If a child...
Bàbá, iyá àti ọmọ ni wọn mọ si Idilé ni Òkè-òkun ṣùgbọ́n ni ilẹ̀ Yorùbá kò ri bẹ́ ẹ̀, nitori ẹbi Eg bàbá, ẹ̀gbọ́n àti àbúrò ẹni, ọmọ, ọkọ àti aya wọn ni a mọ̀ si Idilé. Yorùbá...
View ArticleTọ́jú Ìwà Rẹ Ọ̀rẹ́ Mi – Ọ̀rọ̀-orin lati Ìwé Olóògbé Olóyè J.F....
Ọ̀rọ̀-orin yi jẹ ikan ninú àwọn àkọ́-sórí ni ilé-ìwé alakọbẹrẹ ni ilẹ̀ Yorùbá ni igbà ti ile-iwe àpapọ̀ yè koro. Ṣùgbọ́n ni ayé òde òni, ti gbogbo ilé-ìwé ti kọ èdè abínibí silẹ̀,...
View ArticleATỌ́NÀ LÉDÈ YORÙBÁ – Cardinal Directions in Yoruba
A compass showing the poles in Yoruba language. The image is courtesy of @theyorubablog Originally posted 2013-04-16 19:01:07. Republished by Blog Post Promoter
View ArticlePi pè àti Orin fún orúkọ ọjọ́ ni èdè Yorùbá – Yoruba Days of the week...
http://www.theyorubablog.com/wp-content/uploads/2014/07/Oruko-Ojo-ni-ede-Yoruba-Days-of-the-week.wav Orúkọ Ọjọ́ni èdè Yorùbá Days of the Week In English Àìkú/Ọjọ́ Ọ̀sẹ̀/Ìsimi...
View ArticleẸ̀YÀ ARA – ÈJÌKÁ DÉ ẸSẸ̀: PARTS OF THE BODY – SHOULDERS TO TOES
Download: Parts of the body in Yoruba – shoulders to toes You can also download the mp3 by right clicking here: Parts of the body in Yoruba – shoulders to toes (mp3) Ẹ̀YÀ ARA PARTS OF THE BODY...
View ArticleYí Yára bi Ojú-ọjọ́ ti nyí padà nitori Èérí Àyíká – Effect of...
Ẹlẹkọ-ìjìnlẹ̀ ṣe àkiyesi pe enia ndá kún yí yára bi ojú-ọjọ́ ti nyi padà nitori èérí-àyíká. Ojú-ọjọ́ ti nyí padà lati ìgbà ti aláyé ti dá ayé, ṣùgbọ́n àyípadà ojú-ọjọ́ ni ayé...
View ArticleABD YORÙBÁ – Yoruba Alphabet
“ABD”, ìbẹ̀rẹ̀ iwé kikà ni èdè Yorùbá – Yoruba Alphabets “ABD” is the beginning of Yoruba education. Bi ọmọdé bá bẹrẹ ilé-iwé alakọbẹrẹ, èdè Yorùbá ni wọn fi nkọ ọmọ ni ilé-iwé lati...
View ArticleIwé-àkọ-ránṣẹ́ ni èdè Yorùbá – Letter writing in Yoruba Language
Ni àtijọ́, àwọn ọmọ ilé-iwé ló ńran àgbàlagbà ti kò lọ ilé-iwé lọ́wọ́ lati kọ iwé, pataki ni èdè abínibí. Ẹ ṣe àyẹ̀wò àwọn iwé-àkọ-ránṣẹ́ wọnyi ni ojú iwé yi: Ìwé ti Ìyá kọ...
View ArticleÀwòrán ati pi pe Orúkọ Ẹranko ni Èdè Yorùbá Apá Kini àti Apá Keji...
Bi ó ti ẹ̀ jẹ́ pé a ti kọ nipa orúkọ àti àwòrán ẹranko ni àwọn ìwé ti a ti kọ sẹhin, ṣùgbọ́n Yorùbá ni “Ọgbọ́n ki i tán”, nitori eyi, a ṣe àtúnṣe gẹ́gẹ́ bi “Ọ̀jọ̀gbọ́n Èdè Yorùbá” ti...
View Article“Ìsọ̀rọ̀ ni igbèsi: Ibere ti ó wọ́pọ́ ni èdè Yorùba” – “Questions calls...
Ọpọlọpọ ibere ni èdè Yorùbá bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lu “ọfọ̀ – K”. Yàtọ̀ fún li lò ọfọ̀ yi ninú ọ̀rọ̀, orúkọ enia tàbi ẹranko, ọfọ̀ yi wọ́pọ̀ fún li lò fún ibere. Fún àpẹrẹ, orúkọ enia ti ó bẹ̀rẹ̀...
View ArticleBÍBẸ ÈKÓ WÒ FÚN Ọ̀SẸ̀ KAN: A One Week Visit to a Yoruba Speaking City...
These series of posts will center around learning the Yoruba words, phrases and sentences you might come across if you visited a Yoruba speaking city or state (here Lagos). A sample conversation is...
View Article“Ẹsẹ̀ yá ju mọ́tọ̀ (ọkọ̀) ara ló nfàbò sí” – ohun ìrìn-àjò ni èdè Yorùbá:...
Ni ayé àtijọ́ ẹsẹ̀ ni gbogbo èrò ma nlo lati rin lati ìlú kan si keji nigbati ọkọ̀ ìgbà̀lódé kò ti wọpọ. Ilé Ọba àti Ìjòyè ni a ti le ri ẹṣin nitori ẹṣin kò lè rin ninu igbó kìjikìji ti o yi ilẹ̀...
View Article“Kí Kà ni Èdè Yorùbá” – “Counting or Numbers in Yoruba”
Yorùbá ni bi wọn ti ma a nka nkàn ki wọ́n tó bẹ̀rẹ̀ si ka a ni èdè Gẹ̀ẹ́sì. Ẹ ṣe àyẹ̀wò kíkà ni èdè Yorùbá ni ojú ewé yi: ENGLISH TRANSLATION Counting or numbers in Yoruba before the...
View Article“Ilé làbọ̀sinmi oko” – “Home is for rest after the farm or hard day’s work”.
Bi ènìà lówó tàbi bi kò ni, àwọn ohun kan ṣe pàtàki lati wà ni ílé ki a tó lè pẽ ibẹ̀ ni ilé. Fún àpẹrẹ: ilé ti ó ni òrùlé, ilẹ̀kùn àti fèrèsé; àdìrò àti àdògán; omi: Ki ba jẹ omi ẹ̀rọ, omi òjò tàbí...
View Article