Quantcast
Channel: Learning Yoruba – The Yoruba Blog
Browsing all 1414 articles
Browse latest View live

Àròkọ ni Èdè Yorùbá – Essay in Yoruba Language

Idi ti a fi bẹ̀rẹ̀ si kọ iwé ni èdè Yorùbá lóri ayélujára ni lati jẹ́ ki ẹnikẹ́ni ti ó fẹ́ mọ̀ nipa èdè àti àṣà Yorùbá ri ìrànlọ́wọ́ lóri ayélujára. A ò bẹ̀rẹ̀ si kọ àwọn àròkọ ni...

View Article


“Ìwé àti kọ Yorùba lọfẹ lọwọ Àjàyí Crowther Fún Ra Rẹ”: Learn Yoruba for Free...

Ise Alagba Yoruba, Ajayi Crowther fun ra re. A Yoruba dictionary to look up basic vocabulary     Originally posted 2013-05-23 05:38:56. Republished by Blog Post Promoter

View Article


Bi ọmọ ò jọ ṣòkòtò á jọ kíjìpá: Ibáṣe pọ Idilé Yorùbá – If a child...

Bàbá, iyá àti ọmọ ni wọn mọ si Idilé ni Òkè-òkun ṣùgbọ́n ni ilẹ̀ Yorùbá kò ri bẹ́ ẹ̀, nitori ẹbi Eg bàbá, ẹ̀gbọ́n àti àbúrò ẹni, ọmọ, ọkọ àti aya wọn ni a mọ̀ si Idilé.  Yorùbá...

View Article

“Ìsọ̀rọ̀ ni igbèsi: Ibere ti ó wọ́pọ́ ni èdè Yorùba” – “Questions calls...

Ọpọlọpọ ibere ni èdè Yorùbá bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lu “ọfọ̀ – K”.  Yàtọ̀ fún li lò ọfọ̀ yi ninú ọ̀rọ̀, orúkọ enia tàbi ẹranko, ọfọ̀ yi wọ́pọ̀ fún li lò fún ibere.  Fún àpẹrẹ, orúkọ enia ti ó bẹ̀rẹ̀...

View Article

“Ti ibi, ti ire la wá ilé ayé” –Ọ̀rọ̀ àti Ìṣe Ìgboro ni Èkó: “We came into...

Èkó jẹ́ olú ìlú Nigeria fún ọpọlọpọ ọdún, ki wọn tó sọ Abuja di olú ìlú Nigeria, ṣùgbọ́n Èkó ṣi jẹ́ olú ìlú fún iṣẹ ọrọ̀ gbogbo Nigeria.  Nitori eyi, gbogbo ẹ̀yà Nigeria àti àwọn ará ìlú miran titi dé...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Orukọ́ Ẹranko àti Àwòrán – Yoruba Names of Animals and pictures

Originally posted 2013-06-21 22:30:27. Republished by Blog Post Promoter

View Article

Àwòrán ati pi pe Orúkọ Ẹranko ni Èdè Yorùbá Apá Kini àti Apá Keji...

Bi ó ti ẹ̀ jẹ́ pé a ti kọ nipa orúkọ àti àwòrán ẹranko ni àwọn ìwé ti a ti kọ sẹhin, ṣùgbọ́n Yorùbá ni “Ọgbọ́n ki i tán”, nitori eyi, a ṣe àtúnṣe gẹ́gẹ́ bi “Ọ̀jọ̀gbọ́n Èdè Yorùbá” ti...

View Article

Orúkọ Ẹranko a fàyà fà tabi jomijòkè ni èdè Yorùbá: Names of...

Gẹgẹbi àpè júwe, ẹranko a fàyà fà jẹ ẹranko ti ó ni àwọ̀, omiran ni oro, omiran ni ikarawun, wọn si ńyé ẹyin.  Bi Ejò, àti Ákẽke ti ni oró bẹ̃ ni Àjàpá  àti Ìgbín ni ikarawun. Fún...

View Article


Bi mo ṣe lo Ìsimi Àjíǹde tó kọjá – How I spent the last Easter Holiday

Ìsimi ọdún Àjíǹde tó kọjá dùn púpọ̀ nitori mo lọ lo ìsimi náà pẹ̀lú ẹ̀gbọ́n Bàbá mi àti ẹbí rẹ ni ilú Èkó. Èkó jinà si ilú mi nitori a pẹ́ púpọ̀ ninú ọkọ̀ elérò ti àwọn òbí...

View Article


Àmì – Yoruba Accent

Àmì – ṣe pàtàkì ni èdè Yorùbá nitori lai si àmì, àṣìwí tàbi àṣìsọ á pọ̀.  Ọ̀rọ̀ kan ni èdè Yorùbá lè ni itumọ rẹpẹtẹ, lai si àmì yio ṣòro lati mọ ìyàtọ.  Àmì jẹ ki èdè Yorùbá...

View Article

BÍBẸ ÈKÓ WÒ FÚN Ọ̀SẸ̀ KAN: A One Week Visit to a Yoruba Speaking City...

These series of posts will center around learning the Yoruba words, phrases and sentences you might come across if you visited a Yoruba speaking city or state (here Lagos). A sample conversation is...

View Article

Ẹ̀̀ya orí ni èdè Yorùbá – Parts of Head in Yoruba Language

Orúkọ ẹ̀yà ara ṣe pàtàkì lati mọ nípa kíkọ́ èdè nítorí ó ma nwà nínú ọ̀rọ̀.  Mí mọ awọn orúkọ wọnyi á́ tún jẹ ki èdè Yorùbá yé àwọn ti ó ni ìfẹ́ lati kọ èdè.  A lérò wípé àwòrán àti pípè tí ó wà ni...

View Article

Yí Yára bi Ojú-ọjọ́ ti nyí padà nitori Èérí Àyíká – Effect of...

Ẹ wo àròkọ “Yí Yára bi Ojú-ọjọ́ ti nyí padà nitori Èérí Àyíká” lóri ayélujára ni ojú ewé yi: Check out the essay on “Effect of environmental pollution on rapid climate change” on our...

View Article


“ABD” ni ìbẹ̀rẹ̀ ọ̀rọ̀ ni èdè Yorùbá́ – Alphabets is the beginning of...

Bi ó ti ẹ̀ jẹ́ pé a ti kọ nipa “abd” ìbẹ̀rẹ̀ ọ̀rọ̀ kikọ ni èdè Yorùbá sẹhin, a tu kọ fún iranti rẹ ni pi pè, kikọ àti lati tọka si ìyàtọ̀ larin ọ̀rọ̀ Yorùbá àti ọ̀rọ̀ Gẹ̀ẹ́si. Fún àpẹrẹ,...

View Article

“Ilé làbọ̀sinmi oko” – “Home is for rest after the farm or hard day’s work”.

Bi ènìà lówó tàbi bi kò ni, àwọn ohun kan ṣe pàtàki lati wà ni ílé ki a tó lè pẽ ibẹ̀ ni ilé.  Fún àpẹrẹ: ilé ti ó ni òrùlé, ilẹ̀kùn àti fèrèsé; àdìrò àti àdògán; omi: Ki ba jẹ omi ẹ̀rọ, omi òjò tàbí...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Ògòngò lọba ẹiyẹ” – “Ostrich is the King of Birds”

Ògòngò – Ostrich. Courtesy: @theyorubablog Ògòngò jẹ ẹiyẹ ti ó tóbi jù ninú gbogbo ẹiyẹ, ẹyin rẹ ló tún tóbi jù.  Ọrùn àti ẹsẹ̀ rẹ ti ó gún jẹ́ ki ó ga ju gbogbo ẹiyẹ yoku....

View Article

Tọ́jú Ìwà Rẹ Ọ̀rẹ́ Mi – Ọ̀rọ̀-orin lati Ìwé Olóògbé Olóyè J.F....

Ọ̀rọ̀-orin yi jẹ ikan ninú àwọn àkọ́-sórí ni ilé-ìwé alakọbẹrẹ ni ilẹ̀ Yorùbá ni igbà ti ile-iwe àpapọ̀ yè koro.  Ṣùgbọ́n ni ayé òde òni, ti gbogbo ilé-ìwé ti kọ èdè abínibí silẹ̀,...

View Article


“Kí Kà ni Èdè Yorùbá” – “Counting or Numbers in Yoruba”

Yorùbá ni bi wọn ti ma a nka nkàn ki wọ́n tó bẹ̀rẹ̀ si ka a ni èdè Gẹ̀ẹ́sì.  Ẹ ṣe àyẹ̀wò kíkà ni èdè Yorùbá ni ojú ewé yi: ENGLISH TRANSLATION Counting or numbers in Yoruba before the...

View Article

Ohun ti mo fẹ́ràn nipa Ìsimi Iparí Ọ̀sẹ̀ – What I love about the Weekend Break

Ni ọjọ́ Ẹti, ọjọ́ karun ti a ti bẹ̀rẹ̀ ilé-iwé ni ọ̀sẹ̀, inú mi ma ń dùn nitori ilé-iwé ti pari ni agogo kan ọ̀sán, ti ìsimi bẹ̀rẹ̀. Mo fẹ́ràn ìsimi ipari ọ̀sẹ̀ nitori mo ma nri àwọn òbí mi....

View Article

ÀWÒRÁN ÀTI PÍPÈ ORÚKỌ ẸRANKO, APA KEJI – Names of Wild/Domestic...

Originally posted 2018-03-22 01:59:26. Republished by Blog Post Promoter

View Article
Browsing all 1414 articles
Browse latest View live