Quantcast
Viewing all articles
Browse latest Browse all 1414

Àròkọ ni Èdè Yorùbá – Essay in Yoruba LanguageOriginally Posted on June 15, 2018, last updated on June 15, 2018 and reposted on April 5, 2019

Idi ti a fi bẹ̀rẹ̀ si kọ iwé ni èdè Yorùbá lóri ayélujára ni lati jẹ́ ki ẹnikẹ́ni ti ó fẹ́ mọ̀ nipa èdè àti àṣà Yorùbá ri ìrànlọ́wọ́ lóri ayélujára.

A ò bẹ̀rẹ̀ si kọ àwọn àròkọ ni èdè Yorùbá lati ran àwọn ọmọ ilé-iwé lọ́wọ́ nipa ki kọ àpẹrẹ oriṣiriṣi àròkọ ni èdè Yorùbá àti itumọ̀ rẹ ni èdè Gẹ̀ẹ́si.  A o si tún ka a ni èdè Yorùbá fún ìrànlọ́wọ́ ẹni ti ó fẹ mọ bi ohun ti lè ka a, ṣùgbọ́n kò wà fún àdàkọ.

ENGLISH TRANSLATION

Why The Yoruba Blog is creating a category for Essay in Yoruba language on the internet is to make available on line such resources for those who may be interested.

We shall begin to publish various samples of essay in Yoruba language in order to assist students, interpreted the essay as well as an audio recording of the essay in Yoruba, however, it is not to be copied.

Originally posted 2018-06-15 19:19:46. Republished by Blog Post Promoter


Viewing all articles
Browse latest Browse all 1414

Trending Articles